Kabiyesi
Èmi rábàbà níwájú Oba ñlá
Adàgbà má tè'pá olórúko ñlá
Àìkú àìsá àìpa'pòdà
Ògbóùn tarìgì okùnrín Ogun
Oba mímó
Tó n gbé'bi mímó
Tó n so mímó
Tó n te mímó
Tó n je mímó
Tó n mu mímó
Tó n se mímó
Àwon àgbààgbà mérìnlélógún n pariwo mímó mímó mímó olódùmarè
Alábé'nú ànsásí
Àpáta ayérayé
Oko fún àwon opó
Ògbèjà àwon omo òrukàn
Ògboùntarìgì arúgbó ojó
Ògbe'ni ní'jà
Kó'ní jà ó sa
We worship your majesty!
For you are the God of no impossibility
The Holy Trinity
That takes decision without signing any treaty
Your Lordship cut across every community
For you are the Lord God Almighty
Who reigns in absolute Majesty
When we lost our way, you were our way maker
When we were chained, you were our Chain Breaker
When they thought we had no goals, you were our Goal Setter and getter
What more can we say but to bow down and say *Kaaaabiyesi o*
#HappySunday
ABSOL - 07032277508
ABSOL
Copyright © Oluwasola Elisha | Year Posted 2018
Post Comments
Poetrysoup is an environment of encouragement and growth so only provide specific positive comments that indicate what you appreciate about the poem. Negative comments will result your account being banned.
Please
Login
to post a comment