Get Your Premium Membership

Ojulopesi

Ènìyàn n'sáré àtilà sùgbón, kìràkìtà ò dolà. Omo adáríhurun n'sebí elédùà sùgbón, Oba òkè dáké. Mákànjúolá òré èmi. Ohun tí ò tó léèní yoo sékù lóla. Ojúlópésí, ìyókù d'owó adániwáyé. Sa ipáàre sùgbón má Sàáré àsápajúdé Ànfàní ni'lé ayé jé, a ósì bi é bí o se ti lò. Àkosílè èdá kii tàsé, orí eni ló'ndire. Má gbèrò kii tenì kejì bàjé, sebí oti mo. Ìgbìnyànjú re, Olórun mò si Bópé bóyá, ìyókù yoo dèrò. Mádùúró, Márèwèsì, Ìyókù d'owó eledùà Adébésin Olátúnbòsún

Copyright © | Year Posted 2022




Post Comments

Poetrysoup is an environment of encouragement and growth so only provide specific positive comments that indicate what you appreciate about the poem. Negative comments will result your account being banned.

Please Login to post a comment

Date: 11/27/2024 2:00:00 AM
I wish I could understand this... Meanwhile, I greet you with the love of the Lord, expressed by John 3:16 of the Bible, "For God so loved the world, that he gave his only begotten Son, that whosoever believeth in him should not perish, but have everlasting life." Be blessed.
Login to Reply

Book: Radiant Verses: A Journey Through Inspiring Poetry