Get Your Premium Membership

Ogun

Listen to poem:
(Some words here might not be totally correct because this website does not support all Yoruba letters. Please refer to the audio attached to get the correct reading) Mo fé d'ogún, mo fé d'ogbòn nílé ayé, Ojó a bá p'ojúdé náà l'ódìgbóóse. Òtító sì ni wípé: Ogún tí ò d'ògún lé gbòn t'óbá d'ogbòn, Tàbí kóta l'áàdóta. Bí kò sì rún l'ógòrún, Á rún títí òódúnrún. Àsìkò wa nílé ayé - bi idì tí n fò, Ojó ayé wa - àfi bí àlá, Àní Elédùà nìkan l'ó mon ení máa là. Kìkì kí á ti se rere, K'á sì gbé pèlú ìmò yíì wípé: Bí ìgba wa láyé bá tilè jé òpòlopò ogún, B'ótile wù k'ógùn tó, Ìseun ìfé wa l'áyé omolàkejì, Òun nìkan sáà l'ogún tó dárajù t'a le fi sílè nígbà t'elékò òrun bá polówó síwa. ENGLISH TRANSLATION The quest to be rich and famous, Calls farewell when our eyes close. And this is true: A twenty that is not rusty can get shaky by thirty, Or be burning at fifty. And if it is not blasted at a hundred, It sure will, before three hundred. Our time here - as an eagle that flies, Our life - like a dream. The Almighty alone knows who will succeed. Only for us to do good, And live knowing that: If our lifetime is many twenties, No matter how plenty, Our benevolence and charity alone is the best heritage we can part with, When death calls unto us.

Copyright © | Year Posted 2021




Post Comments

Poetrysoup is an environment of encouragement and growth so only provide specific positive comments that indicate what you appreciate about the poem.

Please Login to post a comment

Date: 2/9/2021 5:43:00 PM
Thanks for sharing your poetry this evening.
Login to Reply
Oroye Avatar
Idowu Oroye
Date: 2/10/2021 10:05:00 AM
You are welcome

Book: Reflection on the Important Things